Kishore Kumar Hits

Sola Allyson - Àjítannáwò́́ - Live lyrics

Artist: Sola Allyson

album: ÌRÌ (The Album Live)


Eni à ba ta k'a fi r'atupa ni mi
Ajitannnawo ti mo da ope l'o ye'Lu
O to mi s'ona t'o ye n gba t'Oba l'ope
Ade, o de mi mo gbe kale niwaju Re
Mo te'ri okan mi ba o s'Olorun mi
(Eni a ba ta)
Eni à ba ta k'a fi r'atupa ni mi
Ajitannnawo ti mo da ope l'o ye'Lu
O to mi s'ona t'o ye n gba t'Oba l'ope
Ade, o de mi mo gbe kale niwaju Re
Mo te'ri okan mi ba o s'Olorun mi
Ajitananwo ti mo da (ope mo mu wa)
Ajitannawo ti mo da (ope mo mu wa)
Irugasoke ko rara (mo s'ope f'Olu)
Anu oluwa lo gba mi o (ope)
Irugasoke ko rara mo s'ope f'Olu
Aanu mo ri gba emi ko ope
Iboju ya ewon bo eru mi fuye
Ile oro ti mo wo ope
Eni à ba ta k'a fi r'atupa ni mi
Ajitannnawo ti mo da ope l'o ye'Lu
O to mi s'ona t'o ye n gba t'Oba l'ope
Ade O de mi mo gbe kale niwaju Re
Mo te'ri okan mi ba o s'Olorun mi
Ago igbala ni mo gbe ope
Maa polongo oro yi titi
Kos'ohun to wa ti Baba ò le tan
Eni wa l'eyin ogba yara wole
Iboju á ya ewon á bo eru re a fuye o
Ile oro l'emi wa ope
Ajitannawo ti mo da (ope)
Ajitannawo ti mo da (ope)
Aanu Oluwa lo gba mi o (ope)
Ko jo pe bayi laa ri o (ope)
Yiyo Eleda ni mo ri o (ope)
Fun gbogbo iranwo ati anfani ti mo n ri lo (ope)

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists