Kishore Kumar Hits

Chief Commander Ebenezer Obey - Ore Se Rere (Juju High-Life Yoruba) lyrics

Artist: Chief Commander Ebenezer Obey

album: 51 Lex Presents Egba (Juju Yoruba)


Odale ore, ewa wo odale ore
To gbe koto si waju to ni kaa ka lo
Se rere o, ore se rere o, dakun o, nitori ola
Se rere o, ore rere, dakun se rere nitori ola
Odale ore, ewa wo odale ore
To gbe koto si waju to ni kaa kalo
Odale ore, ewa wo odale ore
To gbe koto si waju to ni kaa kalo
Se rere yeo, ore se rere o, dakun o, nitori ola

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists