Tipa tikuuku Oluwa mu mi lo shey rere Tipa tikuuku Oluwa mu mi lo shey rere Boya mofe Boya mo ko Oluwa mumi de'be Tipa tiku (tipa tikuuku, oluwa mu mi lo shey rere) Mu mi lo shey rere (tipa tikuuku) tipa tiku (oluwa mu mi lo shey rere) Boya mo fe (boya mo fe, boya mo ko o, oluwa mu mi de'be) Omo Israeli lojo yen oo Tipa tikuuku na fi de'le Ileri Obediedomu gba kamu Opelope apoti eri Josefu iba ma tayo Biwon o ba ta leru lojo yen Oluwa lai fi temi shey Jowo mu mi de'bi ogo Ma fi temi shey (tipa tikuuku) aha (oluwa mu mi lo shey rere) Oluwa ma woju mi rarara (tipa tikuuku) tipa tikuuku (oluwa mu mi lo shey rere) Mu mi lo (boya mo fe, boya mo ko, oluwa mu mi de'be) Omo o ni inakuna ojosi T'ero e ti pin O pada r'oju rere baba Mefiboseti aro ni O pada wa d'eni toun b'oba Jeun Lairotele Maria gba ijise angeli O bi olugbala Olorun lai f'okan si mi Womi de'bi ayo mi Jesu (tipa tikuuku) To ba ti fi was shey (oluwa mu mi lo shey rere) A oni kuro loju kan (tipa tikuuku) olurun wo was (oluwa mu mi lo shey rere) Lo shey rere e (boya mo fe, boya mo ko) boya a ko (oluwa mu mi de'be) ♪ Oluwa ma fi ti ogun idile shey Oluwa ma wo ojo ota ibi ishe mi Oluwa ma fi da do mi se Oruko to o pe mi je omo mi lori Iwo ni oloko ti o nwo oko aiye mi Po mi oluwa de'le ileri Ko je tipa tikuuku Jowo fa mi de bi ogo Ata ye ro o (tipa tikuuku) emi ma be be olorun o (oluwa mu mi lo shey rere) Ma wo to ago mi (tipa tikuuku) Eni go lo po wun mo o (oluwa mu mi lo shey rere) Iwo ni a fi temi shey (boya mode, boya moko) Ma fami lo (oluwa mu mi de'be) (Tipa tikuuku) ni tipa ni tiku (Oluwa mu mi lo shey rere) kini o ba loro wun lele (Tipa tikuuku) olorun (Oluwa mu mi lo shey rere) Fun aye mi (boya mofe, boya mo ko) Boya mo fe (oluwa mu mi de'be) Amin (tipa tikuuku) Tipa tiku (oluwa mu mi lo shey rere) Pariwo ki oluwa mu e lo shey rere (tipa tikuuku) Ah eh (oluwa mu mi lo shey rere) Boya oluwa lo shey rere ni (oluwa mu mi lo shey rere) O ti pe a ti was lojuno (oluwa mu mi lo shey rere)