Oba Salomon, ojo ènin mon wa dobalè Dudu l'ara mi, Émin ninkan bi omonde kekere Alafia, igberaga Kin'le wa ri yin, mon koja ojo irin ti ogun Dudu l'ara mi N'tori eye goolu yin, lowa jishè Alafia, igberaga Ti awon eniyan ton fè alafia Omin wo lo doun, ti igbamin ma koro Omin to tèlé mi si ibikibi ti mon lo Igbami oman doun, igbami oman koro Igbi to tèlé mi si ibikibi ti mon lo ♪ O Kossi Olori kan bi èmin towa ni Afirika Ti koni nin iwariiri foun Agbara to ju agbara eyin Oba Salomon Kossi Olori kan bi emin towa ni Afirika Ti koni nin iwariiri foun Agbara to ju agbara eyin Oba Salomon Omidjè, igbami ma doun, igbami ma koro Omidjè to tèlé mi l'opopona yin Omidjè, ma doun, igbami o ma koro Ominjè lo dja gba min l'onan yin ♪ Oba Salomon, ojo ènin mon wa dobalè Dudu l'ara mi, Émin ninkan bi omonde kekere Alafia, igberaga Kin'le wa ri yin, mon koja ojo irin ti ogun Dudu l'ara mi N'tori eye goolu yin, lowa jishè Alafia, igberaga Ti awon eniyan ton fè alafia Omin wo lo doun, ti igbamin ma koro Omin to tèlé mi si ibikibi ti mon lo Igbami oman doun, igbami oman koro Igbi to tèlé mi si ibikibi ti mon lo ♪ O Kossi Olori kan bi èmin towa ni Afirika Ti koni nin iwariiri foun Agbara to ju agbara eyin Oba Salomon Kossi Olori kan bi emin towa ni Afirika Ti koni nin iwariiri foun Agbara to ju agbara eyin Oba Salomon Omidjè, igbami ma doun, igbami ma koro Omidjè to tèlé mi l'opopona yin Omidjè ma doun, igbami o ma koro Ominjè lo dja gba min l'onan yin.