Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Gedegbe lyrics

Artist: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

album: Amunudun


Wọn ní ká ṣ'iṣẹ l'ásìkò iṣẹ' (iṣẹ', iṣẹ, l'ásìkò iṣẹ')
Wọn ní ká ṣ'eré l'ásìkò eré, eré, eré, eré (eré, eré, l'ásìkò eré)
Ká f'oun tó tọ"jú bọ'jú o, ká f'oun tó tó'mú fín'mú
Wọn ní ká ṣ'iṣẹ' l'ásìkò iṣẹ' (iṣẹ', iṣẹ, l'ásìkò iṣẹ')
A kọ' a ò ṣ'iṣẹ', a mí pè'dè àlọ' (eré, eré, l'ásìkò eré)
Ká f'oun tó tọ"jú bọ'jú, ká f'oun tó tó'rí wé'rí o, wé'rí o
K'ónílé kó ṣọ'lé rẹ', k'ọ'lọ'dẹ' kó gbáradì
Gẹdẹgbẹ' ń bọ' kẹ gbọ', gẹdẹgbẹ ń bọ' lọ'nà
K'ọlọmọ kó tọ'mọ rẹ o, k'ólóun kó yẹ'ra wò
Gẹdẹgbẹ ń bọ kẹ gbọ', gẹdẹgbẹ olórò ọjà oko

Wọn ní ká ṣ'iṣẹ l'ásìkò iṣẹ' (iṣẹ', iṣẹ, l'ásìkò iṣẹ')
Wọn ní ká ṣ'eré l'ásìkò eré, eré, eré, eré (eré, eré, l'ásìkò eré)
Ká f'oun tó tọ"jú bọ'jú o, ká f'oun tó tó'mú fín'mú
Wọn ní ká ṣ'ayé ní pẹlẹ-pẹlẹ (ilé ayé ní pẹlẹ-pẹlẹ)
Ká má f'owó a dípò ìwà
Ká f'oun tó tọ"jú bọ'jú, ká f'oun tó tó'rí wé'rí o, wé'rí o
K'ónílé kó ṣọ'lé rẹ o, kọlọdẹ kó gbáradì
Gẹdẹgbẹ' ń bọ' kẹ gbọ', gẹdẹgbẹ ń bọ' lọ'nà
K'ọlọmọ kó tọ'mọ rẹ o, k'ólóun kó yẹ'ra wò
Gẹdẹgbẹ ń bọ, kẹ gbọ', gẹdẹgbẹ olórò ọjà oko

Ká f'oun tó tọ"jú bọ'jú o, ká f'oun tó tó'rí wé'rí o, wé'rí o
K'ónílé kó ṣọ'lé rẹ o, kọlọdẹ kó gbáradì
Gẹdẹgbẹ' ń bọ, kẹ gbọ', gẹdẹgbẹ ń bọ' lọ'nà
K'ọlọmọ kó tọ'mọ rẹ o, k'ólóun kó yẹ'ra wò
Gẹdẹgbẹ ń bọ kẹ gbọ', gẹdẹgbẹ olórò ọjà oko

Gẹdẹgbẹ olórò ọjà oko

Gẹdẹgbẹ olórò ọjà oko

Gẹdẹgbẹ olórò ọjà oko

Gẹdẹgbẹ olórò ọjà oko

Gẹdẹgbẹ olórò ọjà oko

Gẹdẹgbẹ olórò ọjà oko

Gẹdẹgbẹ olórò ọjà-

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists