Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Akawogbekun lyrics

Artist: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

album: Soundbender


Ojú funfun kọ' nì'wà ire
Bara dúdú kọ'rọ'í, é mà í ṣe t'àìwe
Akáwọgbékùn tó ń wòye kì mà í ṣ'ọ'lẹ
Ṣèbí'nú ló ń rò
(Inú ló ń rò)
Mo sèbí'nú ló ń rò
A kó'ra jọ ń wùwà ibi, tìfunlọ'ràn, wọn ò l'ọ'nà méjì
Ilé à gbé f'ọ'bùn láti ṣọ', bí ò bá dàwó, ìgbẹ' ni yó dì
Igbó ń lá ni yó dà
Moni, ìgbẹ' ni yó dì

Áàrí jẹ, rí mú, rántí ailani
Ẹní tí ń wọṣọ ńlá, rántí oníhòòhò
Àwaayé mọyà, má gbàgbé, pé a ó mo' òun wá
À o ní di lọ
(À òní ko kàn lọ)
À o ni di lọ
Ayáraṣàṣà, ìyẹn lè sá'ré g'òkè
Onísùúrù, ìyẹn á dé'bẹ' dandan, dandan
Ọlọ'gbọn ayé, ìyẹn ń wòye kì mà í ṣọ'lẹ
Ṣèbí'nú ló ń rò
(Inú ló ń rò)

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists