Ẹní rò'fọ' ibi, inú ara rẹ' ni ó jẹẹ' sí Yíó rù, 'yókù lọ sí'lé, ọmọ rẹ' á jẹ ní'bẹ' dandan Ẹni tẹ"bà ọ'tẹ' o, ọbẹ' ẹ'tẹ' ni ó fi jẹ', oh, oh, oh- Àní, yíó rù 'yókù lọ sí'lé, ìran rẹ' á jẹ ní'bẹ' dandan Ò bá dẹ' yọ'wọ' o, yọ'wọ' o nínú ibi Ani o yọ'wọ' o, yọ'wọ' o nínú àìda Ẹkún ìpayínkeke, ní'lé àwọn aṣèbàjẹ' Ọfà oró tí ẹ ta s'ókè, ìyẹn ló padà wá'lẹ' Ẹkún ìjansẹ'mọ'lẹ' o, n'ílé apamọlẹ'kún Òkò ọ'fọ' tí ẹ sọ s'ọ'jà ìyẹn ló dàbọ' wá'lé Ò bá dẹ' yọ'wọ' o, yọ'wọ' o nínú ibi Ani o yọ'wọ' o, yọ'wọ' o nínú àìda ♪ À ngb'èrò kó lè da o (kó lè da o laiye), kí 'bùkún ìlú le kárí Mọ'dàrú f'orí sọ'lẹ', ó ní à fi kí gbogbo rẹ' ó jẹ' t'òun À nṣ'ètò kó lè jọ (kó lè jọ o-) k'ọ'mọdé rí, k'álàgbà rí jẹ Bàsẹ'jẹ' fàáké kọ'rí, ẹ'sín ni ó gbà kẹ'yìn Ò bá dẹ' yọ'wọ' o, yọ'wọ' o nínú ibi Ani o yọ'wọ' o, yọ'wọ' o nínú àìda Ò bá dẹ' yọ'wọ' o, yọ'wọ' o nínú ibi Ani o yọ'wọ' o, yọ'wọ' o- Má ṣe ba wọn kọ' 'lé ẹ'tàn ♪ K'o má ba báwọn jíjó ẹ'tẹ' ♪ Má ṣe ba wọn dín dòdò ẹ'gbin