Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Eniomosin lyrics

Artist: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

album: Keere


Òun ìyá réré ńṣe, o pọ l'ọrọ ọmọ
Wọn a tọ ní s'ọnà, wọn a kọ ní mọ ṣé
Wọn a ṣíṣẹ bí ẹní kíi rẹ nígbà gbogbo
Olùfẹ́ akọkọ, ìyá ní o
Òun ìyá réré ńṣe, o pọ l'ọrọ ọmọ
Wọn a gbé ní jò o, wọn a rè ní lẹ'kún
Wọn a ṣíṣẹ bí ẹní kíi rẹ nígbà gbogbo
Olùfẹ́ òtítọ', ìyá ní o

Òun ìyá réré ńṣe, o pọ l'ọrọ ọmọ
A bà ní s'ọrọ ìwúrí, a gbé ní ro o
Nínú àìní àti ìkorò, kìí dá ní
Olùfẹ́ akọkọ, ìyá ní o
Òun ìyá réré ńṣe, o pọ l'ọrọ ọmọ
À mú ní mọ'na òtítọ' pẹ'lú sùúrù
Wọn a ṣíṣẹ bí ẹní kíi rẹ nígbà gbogbo
Olùfẹ́ òtítọ', ìyá ní o
Ẹni bí'mọ ko mà yọ jú
Ẹni o bí ìyẹn ma bánùjẹ
Ọba òkè o gbàgbé ẹnikánkán o
Ẹni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o
Yeah o, hm-hm, oh, oh
Al'ẹni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o

Ẹni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o
Woah o, hm-hm, yeah-eh-eh
Ṣé bẹ'ni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o

Ẹni bí'mọ ko mà yọ jú
Ẹni o bí ìyẹn ma bánùjẹ
Ọba òkè o gbàgbé ẹnikánkán o
Ẹni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o
Oh-oh, woah-oh-oh, yea-eh-eh
Al'ẹni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o
Ẹni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o
Yeah, eh-eh
Ẹni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o
Ẹni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o
Woah, oh-oh
Ẹni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o

Ẹni ọmọ sìn, ṣé yẹn lo bímọ o

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists