Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Araromi lyrics

Artist: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

album: Oriojori-Eternal Spirits


Mo r'óhun tó wùn mí, arárọ'mí
Ẹlẹ'yinjú ẹgẹ', onítèmi, arẹwà
Ìgbàmíràn t'ó rẹ' mí o, t'ó fẹ' sú mi yé o
Ma ṣe 'rántí ẹ'rín rẹ, ma tú'ra ká o
Mo mà r'óhun tó wùn mí o, arádẹ'mí
Afẹ'rínpanáọ'tẹ', ọlọ'rọ' mi ọmọ ọlà
Ìgbàmíràn t'ó rẹ' mí o, t'ó fẹ' sú mi
Ma rántí àwọn ọ'rọ' rẹ, ma tún 'ra mú o
Wá'lé, wá'lé olólùfẹ' jọ'wọ' o
Dúró, ká jọ máa lò'gbà yì' o
Wá'lé, wá'lé aládùnní baby o
Dúró, ká jọ máa lò'gbà yì' o

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists