Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Se'untoose lyrics

Artist: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

album: Irinajo


Omo o ba ma j'aye ori re l'ode
Ojo mbo wipe o ni le lo'gba
Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri
Oba je a lo'gba yi pe o l'aye
Omo o ba ma s'ise owo re l'odo o
Igba mbo kankan o ni le lakaka
Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri
Oba je a lo'gba yi pe o l'aye
Omo o ba ma j'aye ori re l'ode
Ojo mbo wipe o ni le lo'gba
Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri
Oba je a lo'gba yi pe o l'aye
Omo o ba ma s'ise owo re l'odo o
Igba mbo kankan o ni le lakaka
Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri
Oba je a lo'gba yi pe o l'aye
Se'untoose ore ojo nlo o
Se'untoose ore ojo nlo o
Kirakita o d'ola, seb'ori l'o nla ni
Amose o d'oro eda ni gbe ni
Ani o Se'untoose ore ojo nlo o
Ani o Se'untoose ore ojo nlo o
Kirakita o d'ola, seb'ori l'o nla ni
Amose o d'oro eda ni gbe ni
Omo o ba ma j'aye ori re l'ode
Ojo mbo wipe o ni le lo'gba
Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri
Oba je a lo'gba yi pe o l'aye
Omo o ba ma j'aye ori re l'ode
Ojo mbo wipe o ni le lo'gba
Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri
Oba je a lo'gba yi pe o l'aye
Se'untoose ore ojo nlo o
Ani o Se'untoose ore ojo nlo o
Kirakita o d'ola, seb'ori l'o nla ni
Amose o d'oro eda ni gbe ni ore o
Ani o Se'untoose ore ojo nlo o ye ye ye
Se'untoose ore ojo nlo o
Kirakita o d'ola, seb'ori l'o nla ni
Amose o d'oro eda ni gbe ni ore o
Omo o ba ma j'aye ori re l'ode
Ojo mbo wipe o ni le lo'gba
Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri
Oba je a lo'gba yi pe o l'aye
Omo o ba ma sise owo re l'ode
Egba mbo kan kan o ni le lakaka
Ile aye eda bi iseju akan ma l'o ri
Oba je a lo'gba yi pe o l'aye.

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists