Kishore Kumar Hits

Bode Afolabi - Fun Mi n' iwa Mimo lyrics

Artist: Bode Afolabi

album: Yoruba Most Loved Hymns Vol. 1


Fun mi n' iwa mimo; igbona okan;
Suru ninu iya; aro fun ese;
Igbagbo n'nu Jesu; ki nmo 'toju Re;
Ayo n'nu isin Re; emi adura.
Fun mi l'okan ope; igbekele Krist';
Itara f' ogo Re; 'reti n'n oro Re;
Ekun fun iya Re; 'rora f' ogbe Re;
Irele n'nu 'danwo; iyin fun ranwo.
Fun mi n'iwa funfun; fun mi n'isegun;
'We abawon mi nu; fa 'fe mi sorun;
Mu mi ye joba Re; ki nwulo fun O;
Ki nj' alabukunfun; ki ndabi Jesu. Amin.

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists