Kishore Kumar Hits

Bode Afolabi - Ona Ara L'olorun Wa lyrics

Artist: Bode Afolabi

album: Best of Yoruba Classical Hymns: Igbagbo


1.Ona ara l'Olorun wa,
Ngba sise Re l'aiye;
A nri 'pase Re l'or' okun,
O ngun igbi l'esin.
Ma beru mo, enyin mimo,
Orun t'o su be ni,
O kun fun anu: y'o rojo
Ibukun s'ori nyin.
Mase da Oluwa l'ejo,
Sugbon gbeke re le;
'Gbat o ro pe o binu,
Inu Re dun si o.
Afoju ni alaigbagbo,
Ko mo 'se Olorun;
Olorun ni Olutumo,
Y'o m'ona Re ye ni. Amin.

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists