Kishore Kumar Hits

Pastor J. A. Adelakun - Agbara Olorun Ki Bati lyrics

Artist: Pastor J. A. Adelakun

album: Agbara Olorun Ki I Baati


OLORUN IGBALA
Olorun igbala mo sadi oo
Olorun iwosan, mo kepe o baba
Dina memi okunkun maje kan le bori okan mi oo
Agbara satani atomo ogun re mani ko da san
Ba satani wi layemi
Edumare mo be o ye
Ma se jeki satani raye wonu okan mi
Mo gbe jomi to o wa Jesu sanu funmi
Mo gbe jomi to o wa Jesu gboro mi ro
B'emi okunkun ba parapo to bawa fejomi sun oo
Tejere ni koro baba ko fi dami la re
Back to chorus
Sambalati nbe laye
Tobiah be
Iran Judasi ko tan late
Nse lo ye ka fun ra
Ero buburu tamani ro
Lori Modekai
Gbogbo re lo dasan
Ise Oluwa ni
Ero buburu tamani gba
Lori Modekai
Gbogbo re lo dasan
Igbega lo yori so
Bemi okunkun ba parapo
To ba wa fejo mi sun
T'eje Re ni ko ro Baba
Ko fi damilare
Ibi esu ba gon si
Ninu ile mi too
Ibi esu ba gon so
Lori ise mi o
Agbara No Mercy
Baba fi rojo ina le lori
Satani
Oluwa nba o wi pe ko dehin lehin mi
Dehin, dehin satani dehin lehin mi o
Dehin

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists