Kishore Kumar Hits

Pastor J. A. Adelakun - Gbogbo Aiye Gbe Jesu Ga lyrics

Artist: Pastor J. A. Adelakun

album: Abundant Grace


Angeli ewole fun
Emu ade oba re wa
Se l'oba awon oba
Ti npe ni pepe re
Gbe gbongbo igi, jesse ga
Se l'oba awon oba
Ti a ti rapada
Eki eni t'o gba yin la,
Se l'oba awon oba
Ranti banuje yin
Ete 'kogun yin sese re
Se l'oba awon oba
Ni gbogbo agbaye
Ki won ki, "kabiyesile
Se l'oba awon oba
Lati ma juba re
K'a bale jo jumo korin
Se l'oba awon oba

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists