Kishore Kumar Hits

Lanre Teriba - Mu Inu Mi Dun lyrics

Artist: Lanre Teriba

album: (Prelude) Olodumare


This is Lanre Teriba (Atorise)
Oro to wá ní le yí
Oro to wá ní le yí
Owo lọ ma solve ẹ
Advice kò ooo
E ma f'ejò pá mi
No tension
E yẹ ma pressure mi
Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo
No tension
E ye ma pressure mi
Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo,
Mi ó kánjú waiye
Mi ó ní konju lọ
No long thing ashi ma bá wọn lowo
K' anybody ye ma pressure mi
T'oba nlowo ashi ma báwọn l'owo lowo
Olódùmarè
Olodumare wá mú inú mi dùn
Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje
Olódùmarè
Olodumare wá mú inú mi dùn
Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje
As I no dey here for competition
If you say you pass me no problem
Me too I pass somebody
B'opé b'oyá o ni ile aiye congratulation akárí gbogbo wa
Olódùmarè
Olódùmarè wá mú inú mi dùn
Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje
No tension
E ye ma pressure mi
Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo
No tension
E ye ma pressure mi
Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo
Mi ó kánjú waiye
Mi ó ní konju lọ
No long thing ashi ma bá wọn lowo l'owo
K'anybody ye ma pressure mi
T'oba nlowo ashi ma báwọn lowo l'owo
Olódùmarè
Olódùmarè wá mú inú mi dùn
Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje
Olódùmarè
Olódùmarè wá mú inú mi dùn
Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje
Iya mi ó lowo de bipe wa pin owo kan mi lojo kan
Baba mi o ni ile de bipe wa pin ile kan mi t'obaya
Iyen lo mu mi san sokoto ti mo fi gbogo igba hustle
K'awon omo ti mo bi ma ba ji ya ti mo je
Iyen to mu mi san sokoto ti mo fi gbogo igba hustle
K'awon omo ti mo bi ma ba ji ya ti mo je
No Tension ooo
No tension
E ye ma pressure mi
Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo
No tension
E ye ma pressure mi
Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo
Mi ó kánjú waiye
Mi ó ní konju lọ
No long thing ashi ma bá wọn lowo
Kí anybody ye ma pressure mi
T'oba nlowo ashi ma báwọn l'owo lowo
(E ye ma pressure mi)
(E ye ma pressure mi)
(Mo si ma lowo)

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists