Kishore Kumar Hits

Lanre Teriba - Dansaki lyrics

Artist: Lanre Teriba

album: Dansaki


Dansaki re Ọlọ'run Òkè Ìgbani
Dansaki re oloruko ape rí ire
E mi ó rí ọ rí o ọrùn lọ fi titobi re hàn
A pé júbà ọba oloruko ńlá
Ibà re oba léni bá ni mú ni la lai kúrò lójú kan ṣoṣo
Ibà re o Oba Òkè
Ibà re o Oba Ògo
Ìwọ láwi'mayewun
Ìwọ l'oba tí o ní pekun
Owun ope mi re
Gb'ope mi ti mo mú wá
Èmi elése gb'osuba fún ooo
Gba òṣùba re
Èmi elése gb'osuba fún ooo
Gba òṣùba re
Dansaki re Ọlọ'run Òkè Ìgbani
Dansaki re oloruko ape rí ire
E mi ó rí ọ rí ọ ọrùn lọ fi titobi re hàn
A pé júbà ọba oloruko ńlá

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists