Kishore Kumar Hits

Aṣa - Oré lyrics

Artist: Aṣa

album: Beautiful Imperfection


Má yà 'lé mi ìwọ ọ'rẹ' àtojúbọ' onílé
Má yà 'lé mi ìwọ ọ'rẹ' agbọk'ọlọ'kọ
Má yà 'lé mi ìwọ ọ'rẹ' àdúgbò
Má yà 'lé mi, má yà 'lé k'ọmọ
Ọ'rẹ' tí mo mú bí àbúrò
Ọ'rẹ', Ọ'rẹ' tí mo ṣe dáradára
Ọ'rẹ' tí mo finú hàn
Owá dà mí o, ó tú mi síta
Ó dà bí ọ'rọ' àná
Eh b'ọ'rọ' àná
Don't come to my house
Iwo ọ'rẹ' èké àdúgbò
Don't come to my house
Ìwọ ọ'rẹ' adalérú
Má yà 'lé mi, ìwọ ọ'rẹ' kòfẹ'nifẹ're
Má yà 'lé mi o, Má yà 'lé rara
Ńṣe ni mo lọ wá lọ'jọ' yìí o
Ọkọ tó fẹ'mi sí lé
Kò kú lo wá'ṣẹ' ṣe
Láwọn méjèèjì, wọ'n bẹ'rẹ' ìṣekúṣe
Wọ'n ń hùwà ọmọdé
Wọ'n ṣe bó ṣe wù wọ'n
Ó dà bí ọ'rọ' àná
Eh b'ọ'rọ' àná
Eh dà bí ọ'rọ' àná
Oh b'ọ'rọ' àná
Ẹ wá wo ìjà lọ'jọ' yẹn
Ẹ wá wo èrò tó ń tún tà
Ẹ wá wo ẹ'jẹ' nílẹ'
Ah ọ'rẹ', ọ'rẹ' o, o tú mi síta
Má yà 'lé mi oh-oh-oh
I don't wanna see you no more
Má yà 'lé mi oh-oh
Tẹ' máà béèrè mi n'lé
Ah, má yà 'lé mi oh-oh
I don't wanna see you no more
Ọ'rẹ' ìṣé bùṣe k'ọ'wọ' rẹ o-o
Èmi ò ti ẹ' lè pààyàn

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

V

2022 · album

Similar artists