Kishore Kumar Hits

Olubukunola Bekes - Iranlowo (My Help) lyrics

Artist: Olubukunola Bekes

album: Mighty God


Emi o GBE oju Mi sori Oke wonni
Nibo ni ranlowo Mi,
Yio a ti wa AAA
Iranlowo Mi o todo oluwa wa
Ti o da orun oun aye
Iranlowo Mi latodo re ni oba to da orun aye
Ranmilowo oluwa, ranmilowo
Oun ki yio je ki ese mi koye
Eniti n pamimo kiitogbe beeni kii sun rara oo
E no de sleep huuuuuu
Iranlowo mi latodo re ni, oba to da orun aye, ranmilowo oluwa ranmilowo
Ranmilowo 4x

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists