Kishore Kumar Hits

Tunji Oyelana - Enia Bi Aparo lyrics

Artist: Tunji Oyelana

album: Double Face


Mo lo soko
Mo boluoko
Oni nwa gba Isu
Oro isu ko londun mi
Mo lo sodo
Mo boluweri
Oni nwa gba-eja
Oro eja ko londun mi
Mo de inugbo
Mo boluode soro
Oni nwa gbetu
Oro etu ko londun mi
Mo de buka
Awon ore mi nbuta
Won ni nwa pokele
Oro ebi ko lonse me
Mo ni ya bete
Igba nla nii ti mi
Won ni nwa mu oguro
Oro emu ko lonse mi
Mo wa dele
Mo ba Ronke mi soro o
Oni nwa wora
Oro ara ko lonse mi
Olufe ni baga
Kilo de todorikodo
Ni mba ko
Ni mba ro
Oro gbogbo aiye londun mi
Bo ba o pa o
Lomo araye o
Bi oba o bu lese
Lomo araye o
Bo ba ni lowo
Ka ba eje o
Lomo araye o
Bo si ni mo
Ka ba ese soro
Lomo araye o
Bo ni iwa to da
Ka ba e je o
Lomo araye o
Bi iwa re osi da
Ka yera fun e o
Lomo araye o
Bo ni ise to da
Ka gba mo e lowo
Lomo araye o
Bi o si rise
Ka fi e se yeye o
Lomo araye o
Bo niyawo to da
Ka ba e fe
Lomo araye o
Biyawo e o si da
Ka yimu si e o
Lomo araye o
Ah!
Eniyan bi Aparo
Lomo araye nfe ooo ah
Eniyan bi Aparo lomo araye nfe
Eniyan bi Aparo
Lomo araye nfe ooo ah
Eniyan bi Aparo lomo araye nfe
*Instrumentals*
Bo ba o pa o
Lomo araye o
Bi oba o bu lese
Lomo araye o
Bo ba ni lowo
Ka ba eje o
Lomo araye o
Bo si ni mo
Ka ba ese soro
Lomo araye o
Bo ni iwa to da
Ka ba e je o
Lomo araye o
Bi iwa re osi da
Ka yera fun e o
Lomo araye o
Bo ni ise to da
Ka gba mo e lowo
Lomo araye o
Bi o si rise
Ka fi e se yeye o
Lomo araye o
Bo niyawo to da
Ka ba e fe
Lomo araye o
Biyawo e o si da
Ka yimu si e o
Lomo araye o
Ah!
Eniyan bi Aparo
Lomo araye nfe ooo ah
Eniyan bi Aparo lomo araye nfe
Eniyan bi Aparo
Lomo araye nfe ooo ah
Eniyan bi Aparo lomo araye nfe

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists