(Extra Pro) ♪ Ahh, Ọlọ́run lónìí kò rí bẹ'ẹ' Ọmọ inú mí lo sọ mi dáwo dumate Òkè torí gágára ní pá àṣẹ ré àdipetelè Ìṣòro tó ńdi mí lọwọ, gbọrọ Olùwà kò dá mi níde mí Òkè torí gágára ní pá àṣẹ ré àdipetelè Ìṣòro tó ńdi mí lọwọ, gbọrọ Olùwà kò dá mi níde mí Bàbá wà gbo, o tí rí mí, kò tó dá mí Májẹ k'àyé fọwọ bo'ràwọ̀ mí Bàbá wà gbo, o tí ríi, kò tó dá mí Májẹ k'àyé fọwọ bo'ràwọ̀ mí Tá lọ wà sọ pé kò sí Ọlọ'run? (Tá lọ sọ pé?) Ènìyàn lo sọ pé kọ sí Ọlọ'run Tá lọ wà sọ pé kò sí Ọlọ'run? (Táa, tá lọ, tá lo sọ pé?) Ènìyàn lo sọ pé kọ sí Ọlọ'run Ahh, Ọlọ́run lónìí kò rí bẹ'ẹ' (kò rí bẹ'ẹ') Ọmọ inú mí lo sọ mi dáwo dumate Òkè torí gágára ní pá àṣẹ ré àdipetelè Ìṣòro tó ńdi mí lọwọ, gbọrọ Olùwà kò dá mi nídẹ mí (gbémilékè) Òkè torí gágára ní pá àṣẹ ré àdipetelè Ìṣòro tó ń di mí lọwọ, gbọrọ Olùwà kò dá mi níde mí Bé fẹ, bé kọ, ẹ má gbo ohùn ẹnu mí tọ ń já geere Má gùn ìyán sínú ọdọ, koto Máà sebẹ sínú ẹpò ẹpá, ẹni máyo, àáyo Ọrọ ẹmi at'Ọlọrun láyé mí, kọ ṣe dásí Láti bí ìpẹpẹ lo ń ṣe bẹ'be, kọ ṣe dásí Èmí máà kí ẹ Òkè torí gágára ní pá àṣẹ ré àdipetelè Ìṣòro tó ńdi mí lọwọ, gbọrọ Olùwà kò dá mi níde mí ♪ (It's Bizzle on the mix)