Ah-wa-wa-wa, wa-wa, wa, wa, wa
Gbare (music)
Wa-wa-wa, wa-wa, wa, wa, wa
Áà gbàre
Gbàre-gbàre, kọ lé gbàre òjò gbogbo
Kọ má gbà bí òjò nkan rẹ o, oh-oh-oh-oh-oh
Èmi à gbàre, má gbàre òjò gbogbo
Bò kú òjò kàn, ibí ọnà àlá, ọnà àláa
'Sẹdá mí ẹ̀ya sọrọ, 'ṣẹdá mí eya sọrọ
'Sẹdá mí ẹ̀ya dìde, 'sẹdá mí eya dìde
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ o
Mù mí débẹ, mù mí débẹ, ah, kò tó pé
Ẹyẹlé mí rugbada re bi òkú, ah
Ẹyẹlé mí rugbada, ah
Ẹyẹlé mí rugbada re bi òsá
Ẹyẹlé mí rugbada, ah-wa
Tótún, tòsí l'ẹyẹlé mí fí ko ọrẹ ajé wọlé
Oh-oh, rugbada, eh
Irè ajé kọ wọlé mí, kótún jáde mo, mọ rugbada
Olèlè tó wọnú ẹkọ, ọ tún jáde mọ
È má pẹ rugbada
Gbàre-gbàre kọ lé gbàre òjò gbogbo
Kọ má gbà bí òjò nkan rẹ o, oh-oh-oh-oh-oh
Èmi à gbàre, má gbàre òjò gbogbo
Bò kú òjò kàn, ibí ọnà àlá, ọnà àláa
'Sẹdá mí ẹ̀ya sọrọ, 'ṣẹdá mí eya sọrọ
'Sẹdá mí ẹ̀ya dìde, 'sẹdá mí eya dìde
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ (a-wa, wa-wa)
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ o
Mù mí débẹ, mù mí débẹ (milè), ahh, kò tó pé
Mọ ṣetàn, mọ dìde lá tí wá gbàre te mí
Ọlọ'run míì
Olúbùnkún, olóore tẹ mí, e má kọjá mí Olùgbàlà, ah, ha
Irè iwájú, irè ẹhìn, irè òkè, irè ilè
Irè òtún, irè ósì, kọ má jẹ tèmí Adegbola, ọmọ Akande
Ọrẹ tọ wá ṣe yí Ọlọ́run, jẹ kọ bá wá kalẹ'
K'ọ'tá má ṣe rí wá poṣe
Gbàre-gbàre, kọ lé gbàre òjò gbogbo
Kọ má gbà bí òjò nkan rẹ o, oh-oh-oh-oh-oh
Èmi à gbàre, má gbàre òjò gbogbo
Bò kú òjò kàn, ibí ọnà àlá, ọnà àláa
'Sẹdá mí ẹ̀ya sọrọ, 'ṣẹ̀dá mí ẹ̀ya sọrọ
'Sẹdá mí ẹ̀ya dìde, 'sẹdá mí ẹ̀ya dìde
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ o
Mù mí débẹ, mù mí débẹ, ahh, kò tó pé
(I am Eazy productions)
Ẹyẹlé mí rugbada re bi òkú, ah
Ẹyẹlé mí rugbada
Поcмотреть все песни артиста