Wan lọ gb'ẹbọ ni oríta mẹta Nitori awa Wan ko jẹ ki babalawo ko simi lalẹ Nitori awa Wan ba kuro ni shọshi wan gba'le ra daun shelọ Nitori awa Eku ina'wo ẹran pipa l'ojo jumọ Nitori awa Wan ma gb'ẹbọ wan ni ihoho lo gan jọ oru Nitori awa T'aba wi tan wan ma gbe bíbélì ọrọ kiri Nitori awa Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo Kuru kẹrẹ Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun Ogun o ran wa o Ẹ ma wulẹ sáré ka Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo Kuru kẹrẹ Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun Ogun o ran wa o Ẹ ma wulẹ sáré ka