Kishore Kumar Hits

King Sunny Ade - Ma Korin Titun lyrics

Artist: King Sunny Ade

album: Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide


Maajo maa Korin titun
Maajo maa Korin titun
Bi nba ti ri eni bi eni eyan bi eyan
Bi Tolanrewaju Kazeem
Maajo o maa korin titun
Maajo maa korin titun
Maajo maa korin titun
Bi nba ti ri eni bi eni eyan bi eyan
Bí Tolanrewaju Kazeem
Maajo maa korin titun
Ebami pe aare kingbo
Aare o
Lanrewaju njaye e lo were were
Eni o dunmo o gbodo so faraye gbo
Omo Kazeem naa re o eni re ni
Bobagunwa ijebuland
Omo ayegbami
Omo arigbabuwo
Chief Shakiru mi atata
Olanrewaju omo Kazeem aguntasholo
Araba ni baba eni a ba laba ni baba
Chief Bobagunwa gbogbo Ijebuland
Chairman jokers industries
Original chairman Ijebu Igbo club
Omo oloye ayegbami
Omo arigbabuwo
Iya mo nba ro de
Lanrewaju njaye e lo were were
Eni o dun mo o gbodo so faraye gbo
Omo Kazeem na re o eni re ni
Bobagunwa Ijebuland
Omo ayegbami
Omo arigbabuwo
Maa gbadun ni ti e
Chief Olanrewaju Kazeem
Imule tani imule kabiyesi
Oba toto bi aro
Oba regbe bi osu
Kade pe lori ki bata pe lese oba alase
Oba Sikiru Adetona
Ogba gba ragba te wole
Omo apokusa gere gere laya
Araba ni baba eni a ba laba ni baba ni Jebu ode
Imule ta ni imule
Oba toto bi aro
Oba regbe bi osu alaye
Oba Adetayo Opakutu baba nile
Baba loko ni baba Jebu Igbo mo se ba
Kabiyesi alase
Lanrewaju maa gbadun ni tire
Ko se wu legberun eko
A fi aidun o be
Baba Marticat, Bisola aya Adepetu londo egi mogun
Olowo ori oko Alhaja Rihanat Abeje mama Shafawu Omowale
Olowo ori Alhaja Idaya Abike mama Shaki Olatilewa
Olowo ori oko Alhaja Kudirat Abeni mamaTaofiki Oladiran
Ban ba bu e leyin ma se binu rara rara
Ban ba bu e loju e mase binu rara Lanrewaju
Agba ti o binu lomo re npo jojo o
Ko ma fa si won leti wipe
Eyin oju lafe ni
Eyin a soro eni leyin
Wi fun won pe
Eyin oju lafe ni
Eyin a soro eni lehin
Gbogbo yin le o fori bale fun Lanrewaju
Be fe be ko odi tulasi
Olarewaju aguntasolo
Lanrewaju aguntasolo
Epe aare, aare ajagugu
Opo aare, aare ejebo oda
Aare o pe kogun ma jalu e je a mi
Aare o pe kogun ma jalu e je a mi o
Oke agbo logun o gbodo ja
Aare we lodo gbogbo omode yo wo o se
Won ni temi ni o gba Lanrewaju temi ni o gba
Shakiru mi omo dara o de jo
Shakiru mi omo dara o de jo
Nba jo binrin ni nba ti ka e mole
Aijo binrin dun mi o nba ti ka e mo de de
Bo ya wale ba mi tage kin le bimo to jo e
Olarewaju

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists