Kishore Kumar Hits

King Sunny Ade - E Yi Ga lyrics

Artist: King Sunny Ade

album: Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide


Adeniyi lo nki yin o

A gbe t'ano danu, a gbe tuntun de
Eyi ga (ah), oga lagaju, eyi ga
A gbe t'ano danu, a gbe tuntun le
Eyi ga, oga lagaju, eyi ga
E ma gbo
Iye ni ye eyele, iye ni ye eyele o
Irubo ni raga ba l'orun
Ayo mi k'ale o jare ni'le aye
A ye mi l'oke okun
A ye mi n'ile Naija
A ye mi l'ode agbaye
Ati ile ti mo n gbe
A ye mi l'oke okun
A ye mi n'ile Naija
A ye mi l'ode agbaye
Ati ile ti mo n gbe
Ati inu ile ti mo n gbe
(Ati inu ile ti mo n gbe)
Ati inu ebi ti mo ni (aje)
A ye mi l'oke okun
A ye mi n'ile Naija
A ye mi l'ode agbaye
Ati inu ile ti mo n gbe

A gbe t'ano danu, a gbe tuntun le
Eyi ga, oga lagaju, eyi ga
African beat, tutntun la gbe de
Eyi ga, oga lagaju, eyi ga
Iye ni ye eyele ni raga ba l'orun
Eyi ga

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists