Kishore Kumar Hits

King Sunny Ade - Omo Se Koko lyrics

Artist: King Sunny Ade

album: Check "E"


Lat'orun l'okunrin ti l'oyun sinu
Won de'le aye na bi fun obirin

Lat'orun l'okunrin ti l'oyun sinu
Won de'le aye na bi fun obirin
Obinrin a l'oyun e fun osu mesan
Ko to bi l'omo

Obinrin a l'oyun oyun fun osu mesan
Ko to bi l'omo
Tori kini, tori omo la gbe jo k'ale, omo ni iyi eni
Ara, omo se koko l'aye
Edumare ko fun wa ni t'awa

Omo se koko l'aye
Edumare ko fun wa ni t'awa
Okunrin abiro, Obinrin abiye

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists