Kishore Kumar Hits

TROD - Lazy Nigerian Youth lyrics

Artist: TROD

album: Lazy Nigerian Youth


Ehhh
Yaaa
Hum
What di do
Yaaa
Hum
So èmi ṣì máa sa dua fún àwọn tèmi
Wole ileya Kari gan
Ìjọba tí feje riwa, ẹri ban ṣe parí gan
Tomode tagba kúrò nilu wọn salo s'Abidjan
Nobody lazy for here even olè wey dey carry gun
Àwọn ọmọ yín wá overseas, all of them are having fun
And all of my ghetto boys still working under the sun
Koma sere nigboro, ero oro yin ye keto so
EFCC were yẹn na ọ'rọ' yahoo Boys lo ma rí sọ
Àwọn idiot fellows àwa wí tán wọn lọ ń dá sopa
Wọn mon pé èmi kan san salary fún oga Ọlọpa
Padi mi tó Pupa tí dúdú owu lọ kú
Ẹyin ijoba were yi ejò kí lè wúlò fún
Eyan kan ló ní billion, Eyan kan ló ní trillion
Mo dé mọ pe dream Eyan kan nù yín ní kó ni zillion
You dey inside AC you talk say na the youth lazy
Inú iná lè má wo, O sure mi pé Ema rí bí de sí
Ema diwo ẹni body ẹni bama sase má sase
Eti gbàgbé nígbà tí òyìnbó tí sopolo wá d'ase
Ejò tó gbé 36 milly, ejoo ni nibo lowa?
Ko jeje pe Mushin, Bariga Taboshodi lo wa
Oshodi, Oshodi, Oshodi, Oshodi óò, wọlé pelu change ẹ, mio ni
Change óò, to bá ní change má wọlé óò, mi ò ní change óò
So, President Buhari ojú sì má tún rà rí
Ẹ'fọ'n mú ẹ'jẹ' bí coldstone, a tún rowo ra túrari
Ọjọ' jumo lè má ń rerin tá bá rí yín ní TVC
Ebi ń pa mekunnu ẹni kan ló ṣe PVC
Kò sí ìṣe nigboro làwọn graduate fi ń gbé lapi
Tori won mo pe táwọn bá sase wọn mà be happy
Aṣo rock láṣebi ń gbé, inú ẹ gangan lọ tá wá
Naija ni kan ni mo ti má gbó penu kininhun lowo wá
Wọn lé kò SAS sì gboro àwọn yẹn anti robbery
Gbogbo innocent citizens pátá na ti nobi
Meek Mill jáde kúrò ní prison ó look chubby
May peace be upon my people ẹyin ogologo Anobi
To bá san ra bí DJ KHALED tó ń look fìrìfìrì
Ó má digbale agbepo kúrò ní kirikiri
Ẹ'jẹ' wá lójú anybody ìyá ń jẹ' wá gan
To bá dé gboro, wá rẹ ni to lagbo ju Fela Lo
Naija nìkan na má ń fún l'award fún corruption
Ko ṣe fault wá àwọn ìjọba wá lọpọlọ wọn ṣàn
Má Kira fún àwọn tèmi
Má júbà fún àwọn tèmi
Ìwọ tó bá gba wire na, invest lo fun awon temi
K'awọn tèmi ó ròhun jẹ je Everyday
Because it's not easy we expect a good day
Ìjọba change lafe, afe changi
Ejo ewa ikan shey si level yi

Поcмотреть все песни артиста

Other albums by the artist

Similar artists