Eleko'dere ṣebo o lo jere Eleko'dere ṣebo o lo jere Eleko'dere ṣebo o lo jere Eleko'dere ṣebo o lo jere O n ro'ṣọ dudu, o si n ro'ṣo pupa O n ro'ṣo dudu o si n ro'ṣo funfun O faimu gbaja o si tun lekenka o Eleko'dere ṣebo o lo jere Eleko'dere ṣebo o lo jere Eleko'dere ṣebo o lo jere Eleko'dere ṣebo o lo jere Eleko'dere ṣebo o lo jere O n ro'ṣọ dudu, o si n ro'ṣo funfun O n ro'ṣo dudu o si n ro'ṣo pupa O faimu gbaja o si tun lekenka o Eleko'dere ṣebo o lo jere Asiko Eledumare lo dara (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ) Asiko Eledumare ni yẹni (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ) Ani ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ) Asiko Eledumare lo dara (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ) Ọrẹ ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ) Kii ṣe ti ka joko jẹbẹtẹ Kii ma i ṣe ti ka joko rẹgẹdi Iṣẹ ń bẹ pupọ lati ṣe Kii ma i ṣe ti ka joko bẹbẹrẹ Kii ṣe ti ka joko rọbọtọ Iṣẹ ń bẹ nilẹ lati ṣe Asiko Eledumare lo dara (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ) Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ) Asiko Eledumare ni yẹni (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ) Ani ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ) Asiko ti to ara mi o, asiko ti to Asiko ti to ara mi o, asiko ti to Asiko ti to fun wa o Ara mi, asiko to to fun wa o Ka bo l'oko ẹru (asiko ti to fun wa o) Ka bọ'wu iya sọnu (asiko ti to fun wa o) B'iṣẹ o ba pẹni o (asiko ti to fun wa o) Ṣeb'ẹnikan i pẹ'ṣẹ (asiko ti to fun wa o) Ka bo l'oko ẹru (asiko ti to fun wa o) Ka bọ'wu iya sọnu (asiko ti to fun wa o) B'iṣẹ o ba pẹni o (asiko ti to fun wa o) Ṣeb'ẹnikan i pẹ'ṣẹ (asiko ti to fun wa o) Asiko ti to fun wa o Ka bo l'oko ẹru (asiko ti to fun wa o) Ka bọ'wu iya sọnu (asiko ti to fun wa o) B'iṣẹ o ba pẹni o (asiko ti to fun wa o) Ṣeb'ẹnikan i pẹ'ṣẹ (asiko ti to fun wa o) Ka bo l'oko ẹru (asiko ti to fun wa o) Ka bọ'wu iya sọnu (asiko ti to fun wa o) B'iṣẹ o ba pẹni o (asiko ti to fun wa o) Ṣeb'ẹnikan i pẹ'ṣẹ (asiko ti to fun wa o) Asiko ti to fun wa (asiko ti to fun wa o) Asiko ti to fun wa ...