Ibi ori da ni si laa gbe o, Akin omo Ibi a gb'ese le n lo ye k'ese te Ibi ori da ni si laagbe o Ibi a gb'ese le n lo ye k'ese to Al'ori re a fi're (a fi're a fi're) Ese ibi ire ni o wo la'ye o o o Al'ori re a fi're o o o (a fi're a fi're) Ese ibi ire ni o wo, o ni sina lai lai O ti ja'we olubori o, Akin omo O d'eni a ji ri, a dun wo O ti ja'we olubori o, omo agba ti nso laakaye Le s'ebo, le soogun l'aye (sebo, le sogun) B'a se w'aye paa ri laa ri o O ba de le s'ebo k'o s'ogun to gbona (sebo, le sogun) Ise owo eni se yen ni ngbe ni l'eke l'aye ♪ Ibi ori da ni si laa gbe o Akin omo Ibi a gb'ese le n lo ye k'ese te Ibi ori da ni si laagbe o Ibi a gb'ese le n lo ye k'ese to Al'ori re a fi're (a fi're a fi're) Ese ibi ire ni o wo la'ye o o o Al'ori re a fi're o o o (a fi're a fi're) Ese ibi ire ni o te, o n sina lai lai Le s'ebo, le soogun bami (sebo, le sogun) B'a se w'aye paa ri laa ri o O ba de le s'ebo k'o s'ogun to gbona (sebo, le sogun) Sebi ise owo eni iyen ni ngbe ni l'eke l'aye ♪ O ti ja'we olubori o O ti ja'we olubori o O ti ja'we olubori o