Erure to ba oo Erure to ba oo Oba to s'oro ti ina yo Erure to ba oo Erure to ba oo Erure to ba oo Olorun to s'oro ti ina yo Erure to ba oo Erure tooo ba Erure too ba oo Olorun to s'oro ti ina yo Erure to ba oo Olorun to s'oro ti ina yo Erure to ba oo Iwo to s'oro ti okun pupa gbe o Erure to ba oo Iwo to s'oro tokun pupa La oo Erure to ba oo Iwo to s'oro ti ina yo Erure to ba oo Iwo to s'oro ti ina yo oo Erure to ba oo Iwo to fi idin je odindi oba Erure to ba oo Erure to ba olorun oo Erure to ba oo Ah ah Iwo to so Estheri d'ayaba lojiji Erure to ba oo O mu eru kuro laarin eru O wa so eru d'oba ti gbogbo aye n wari fun Erure to ba ooo Olorun to s'oro ti ina yo o Erure to ba oo Olorun to s'oro ti ina yo o Erure to ba oo Eleda to s'oro ti ina jade Erure to ba oo O mu omi jade ninu apata wa Ta lo da bi re o Erure to ba oo O se oun t'enikan o le se aye raye Erure to ba oo Olorun to s'oro ti ina yo o Erure to ba oo Olorun to tun aye awa naa se Erure to ba oo Eni ta ti ro pe ko le pa go wa deni to kole ala ruru aah ha Erure to ba oo Aya re too ja yan Aya re too ja yan olori aye Erure to ba oo Ooh Aya re ja mi yee ye Erure to ba oo Ogo re yio po oooo Erure to ba oo Erure to ba oooo Erure to ba oo Eru re to ba oooooo Erure to ba o Erure to ba oo Erure to ba oo