Emi mo oun oju mi tiri Mo mo oun eti mi ti gbo Mo oun oju mi tiri Mo mo oun eti mi ti gbo Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala Aiye mi le to Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala Aiye mi le to Mo mo oun aiye ma ti wi Mo mo oun eyan ma ti so Won ti pe wa ni agan ri Boya won ti pewa lo'olosi ri Sugbon, Logan ti o de o Olugbala, aye e le to Sugbon, Logan ti o de o Olugbala, aye e le to Aye to ti daru tele tele o Logan ti o de Oro ti eniyan ti fi s'alufani re Logan ti o de Oro ti ko dara ta ti so si o Logan ti o de Oruko ti kin se tire ta ti pe o Logan ti o de Ani logan ti o de o Olugbala aye e le to Logan ti o de o Olugbala Aye e le to Logan ti Jesu de o Olugbala L'aye e le to Ko s'oruko t'aye o le pe ni Wa ma peni l'agan l'ona gbo gbo Bo ba lowo lowo agan n Bo ba bi mo o agan ni Bo ba tegba ko dagba agan lo je Sugbon logan ti o de Sope logan ti o de Ani logan ti o de, lesekese Logan ti o de Ahah, logan ti o de o Olugbala L'aye e le to Logan ti o de o Olugbala L'aye e le to Instantly lo'n je be Bo se n debe Won de yi oruko pada Logan ti o de, eheheh logan ti o de Eyin ta pe l'agan e ma so wi pe Logan ti o de Awon ta ti fi oruko aburu pe ni'le won yi Logan ti o de Ani logan ti o de o Olugbala, l'aye mi le to Logan ti o de o Olugbala L'aye mi le to Ani eheh, logan ti o de o Olugbala L'aye mi le to Ani, logan ti o de o aseda L'aye mi le to Ani, logan ti o de o Olorun o L'aye mi le to Irawo owuro omo Mary yo sinu oro mi, l'aye mi le to Ah, alagbara ni Shiloh loba ran ti mi si rere, l'aye mi le to Enu mi wa kun fu eri o gbogbo, l'aye mi le to Aye mi gba iyipada otun o logan to de, l'aye mi le to Aye mi ba leto l'ota ba wo Iran mi, l'aye mi le to Aye mi le to lo ta bawo Iran mi, l'aye mi le to Ota kaworo, enu won gbe tan lori oju kan, l'aye mi le to Ahah, logan ti o de o Olugbala, l'aye mi le to Thank you Lord Jesus for all you've done