Ibile! Chinko; ah ah We' only talking money Ab'o ja? Mo ma f'ilefo t'oju yin mo'le bi Baddi Osha Although mo wa n Gucci Gang But am a F.uckking holigan Nighhar trynna find me but they don't know Where the F.uckk am at (CHORUS) Bo ba le d'ogun ko d'ogun Bo ba le d'ija ko d'ija- ko d'ija... Bo ba le d'ogun ko d'ogun Bo ba le d'ija ko d'ija- ko d'ija... Bo ba le d'ogun ko d'ogun Bo ba le d'ija ko d'ija- ko d'ija... Bo ba le d'ogun ko d'ogun Bo ba le d'ija ko d'ija- Bodija... Bo ba le d'ija ko d'ija (VERSE 1- Chinko Ekun) Tiger ti wole de; mi o gbese ran anybody Efficient enough; mi o gbese fun anybody Ibile lawa; eruku ni mo ba to T'on fi bante se waist trainer T'on fi iwo malu se walkie-talkie A l'O Shapranpran; e n form lion Iya yin n de n sa f'aja Yepa; mo ni pe am a man of virtue Ani mo rap gan Okorocha, erect my statue Mo ni bo ba le d'ogun ko d'ogun Bo ba le d'ija ko d'ija Mi o le ka iye awon demons loru t'on ma n bami ja Water no get enemy; ko seni t'o b'omi ja Eni ja'we s'enu, k'o sa ready lati b'Odi ja D'isu ata yan-yan; enemies o fe gboran Stop acting up; you too old for me Afi bi Kanran Eti mi n mo fi n ri ira, oju ni mo fi n gboran Tele, bashu bashu anyhow bi omo ti o n'iran Tiger RePeat (HOOK) & (CHORUS) (Reminisce- VERSE 2) Chinko; omo mi you gon' shine when gon' shine Philosophy temi ni pe "nobody's taking what's mine" Oro hip hop yi ti pe gan Mo n ba bo lat'aye Fugu Lai pe, you gon' pull up in my crib; Been there, you know Erin ke-ke when I hear these nigghers talking money Saye gbangban wa ba mi; nigghers, You gat something for me? Ma ni k'awon Menomo dunbu e You ain't gat nothing on me Ninu ere Fuji yi, man mi, ain't nobody fallen on me Yeba; to ba d'ogun, ko d'ogun To ba d'ija, ko d'ija T'o ba de n wa battle ground Omo, mo wa n Bodija O ma ti mo iyen tele; mi o n f'aye lo f'osi sa T'o ba ti ka l'oju e, oya, ki n to laju k'o ti ka A ma s'idi; t'o ba de tun pe, mo ma ni k'on fi e ka scores Emi o worry n pa future, awon Chinko ti assure mi Legacy mi wa n le, awon Chinko ti secure mi RePeat (HOOK) & (CHORUS) (Reminisce/Chinko- VERSE 3) Ibile Movement A n k'eruku wo caravan Lati kekere l'awon omo mi ti di Jagaban 7 years *deep*, won si n kaye je bi Tuwo Anybody t'o ba test, o mo, e ni duro Mo n chill pelu Alaga A n joko sori high table Oni Furniture n binu cos every show, we buy table Sare ba mi se wire; I don't need to buy cable Oponu t'o organise; were to ni time table I know niggher, this topic is not for discussion Gbe won poyi anyhow bi eni t'o fe se excursion Ibile Ibile Ibile Ibile; you already know that So far ti n ba wa laye, omo, mi o le di throw-back Ah ahh E gba mi o; mi o mo ila t'owo ko Lyrics enu mi- divine Blowing mi- na follow come Pansa o fura, pansa jana; aja o fura, aja jin Ko si b'o se buru to, o ma b'agbon ni Badagry RePeat (HOOK) & (CHORUS) (OUTRO)